Dele Giwa: Èyí ni àlàyé bí wọ́n ṣe fi àdó olóró pa àgbà akọ̀ròyìn yìí lásìkò ìjọba olọgun

Bi a ba ni ka maa p'ori akọni laarin awọn akọroyin orile-ede Naijiria, ko si igba ti ida Dele Giwa ko ni lalẹ gaaraga.Olootu agba iwe iroyin Newswatch ni Giwa, o si jẹ ọkan lara awọn akoroyin ti o dantọ ni Naijiria ki ọlọjọ to de.Ọrọ iku rẹ jẹ nnkan to ṣokunkun titi di bi a ti ṣe n sọrọ yii.Orisirisi alaye si ni awọn eeyan ti fi sita lati na ika si awọn ti wọn lero pe o lọwọ ninu iku rẹ.

Bi a ba ni ka maa p'ori akọni laarin awọn akọroyin orile-ede Naijiria, ko si igba ti ida Dele Giwa ko ni lalẹ gaaraga.

Olootu agba iwe iroyin Newswatch ni Giwa, o si jẹ ọkan lara awọn akoroyin ti o dantọ ni Naijiria ki ọlọjọ to de.

Ọrọ iku rẹ jẹ nnkan to ṣokunkun titi di bi a ti ṣe n sọrọ yii.

Orisirisi alaye si ni awọn eeyan ti fi sita lati na ika si awọn ti wọn lero pe o lọwọ ninu iku rẹ.

A ko ridi eyikeyi awọn alaye yi fi mulẹ ṣugbọn ohun ti ko ruju ni pe ado oloro ni wọn fi pa Dele Giwa eleyi ti wọn gbe sinu apo ifiweranṣẹ si ni.

Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan pẹlu BBC, Kayode Soyinka to jẹ olootu iwe iroyin Newswatch ni London sọ pe oun ati Dele Giwa jijọ wa nile rẹ ni GRA lọjọ kọkandinlogun, oṣu Kẹwaa, ọdun 1986 ni.Iyawo Dele Giwa, Funmilayo gẹgẹ bi Kayode ti ṣe sọ gbe akara fun wọn ti wọn si jijọ n ṣaroye nipa bi awọn ọtẹlẹmuye ti ṣe fọrọ wa Dele Giwa lẹnuwo ṣaaju ọjọ naa.

Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan pẹlu BBC, Kayode Soyinka to jẹ olootu iwe iroyin Newswatch ni London sọ pe oun ati Dele Giwa jijọ wa nile rẹ ni GRA lọjọ kọkandinlogun, oṣu Kẹwaa, ọdun 1986 ni.

Iyawo Dele Giwa, Funmilayo gẹgẹ bi Kayode ti ṣe sọ gbe akara fun wọn ti wọn si jijọ n ṣaroye nipa bi awọn ọtẹlẹmuye ti ṣe fọrọ wa Dele Giwa lẹnuwo ṣaaju ọjọ naa.

Ṣaa deede ni wọn gbọ ti eeyan kan n kan ilẹkun ti ọmọ Dele Giwa, Kayode si wa jiṣe apo iwe naa fun Dele Giwa lọjọ naa.

Kete ti Dele Giwa ṣi apo iwe yii ni ado oloro bu gbamu ti o si gbina jẹ.Ori ko Kayode Soyinka yọ ninu ibagbamu ado oloro naa amọ o farapa diẹ.

Kete ti Dele Giwa ṣi apo iwe yii ni ado oloro bu gbamu ti o si gbina jẹ.

Ori ko Kayode Soyinka yọ ninu ibagbamu ado oloro naa amọ o farapa diẹ.

Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan pẹlu BBC, Kayode Soyinka to jẹ olootu iwe iroyin Newswatch ni London sọ pe oun ati Dele Giwa jijọ wa nile rẹ ni GRA lọjọ kọkandinlogun, oṣu Kẹwaa, ọdun 1986 ni.Ọjọ buruku, Eṣu gbomi mu naa bọ si ọjọ Aiku.Iyawo Dele Giwa, Funmilayo gẹgẹ bi Kayode ti ṣe sọ gbe akara fun wọn ti wọn si jijọ n ṣaroye nipa bi awọn ọtẹlẹmuye ti ṣe fọrọ wa Dele Giwa lẹnuwo ṣaaju ọjọ naa. Ṣaa deede ni wọn gbọ ti eeyan kan n kan ilẹkun ti ọmọ Dele Giwa, Kayode si wa jiṣe apo iwe naa fun Dele Giwa lọjọ naa. Kete ti Dele Giwa ṣi apo iwe yii ni ado oloro bu gbamu ti o si gbina jẹ. Ori ko Kayode Soyinka yọ ninu ibagbamu ado oloro naa amọ o farapa diẹ.Toun ti pe wọn tara ṣaṣa gbe e lọ si ile iwosan, Kayode sọ pe ibẹ ni o dakẹ si.Nigba ti iṣẹlẹ yi waye lọdun 1986, Naijiria si wa labẹ ijọba ologun labẹ akoso Ọgagun Ibrahim Babangida.Igba akọkọ si re e ti wọn yoo fi ado oloro pa eeyan ni Naijiria.Iṣẹlẹ naa titi di oni jẹ eleyi ti awọn eeyan ṣi fi n ṣakawe ewu to wa nibi iṣẹ akọroyin ni Naijiria.

Ọjọ buruku, Eṣu gbomi mu naa bọ si ọjọ Aiku.

Iyawo Dele Giwa, Funmilayo gẹgẹ bi Kayode ti ṣe sọ gbe akara fun wọn ti wọn si jijọ n ṣaroye nipa bi awọn ọtẹlẹmuye ti ṣe fọrọ wa Dele Giwa lẹnuwo ṣaaju ọjọ naa. Ṣaa deede ni wọn gbọ ti eeyan kan n kan ilẹkun ti ọmọ Dele Giwa, Kayode si wa jiṣe apo iwe naa fun Dele Giwa lọjọ naa. Kete ti Dele Giwa ṣi apo iwe yii ni ado oloro bu gbamu ti o si gbina jẹ. Ori ko Kayode Soyinka yọ ninu ibagbamu ado oloro naa amọ o farapa diẹ.

Toun ti pe wọn tara ṣaṣa gbe e lọ si ile iwosan, Kayode sọ pe ibẹ ni o dakẹ si.

Nigba ti iṣẹlẹ yi waye lọdun 1986, Naijiria si wa labẹ ijọba ologun labẹ akoso Ọgagun Ibrahim Babangida.

Igba akọkọ si re e ti wọn yoo fi ado oloro pa eeyan ni Naijiria.

Iṣẹlẹ naa titi di oni jẹ eleyi ti awọn eeyan ṣi fi n ṣakawe ewu to wa nibi iṣẹ akọroyin ni Naijiria.

Adajọ agba ni ile ẹjọ giga ti ijọba apapọ niluu Abuja, Inyang Ekwo ti pasẹ fun agbẹjọro agba lorilẹede Naijiria to tun jẹ minisita fun eto idajọ pe ki iwadii bẹrẹ pada lori iku gbajugbaja akọroyin, Dele Giwa.Nigba to n gbe idajọ kalẹ, Adajọ Ekwo sọ pe wọn gbọdọ pese awọn to lọwọ ninu iku awọn akọroyin lorilẹede Naijiria.Ọdun 1986 ni Dele Giwa jade laye lẹyin to tẹwọ gba ado oloro ti wọn fi sinu lẹta ni ọfisi rẹ nipinlẹ Eko.Yatọ si igbẹjọ nipa Ọgbẹni Giwa, ile ẹjọ ọrọ naa kan gbogbo awọn to lọwọ ninu iku awọn akọroyin to n sisẹ wọn, ki wọn si fi iya jẹwọn ni ilana to ba ofin mu .Adajọ Ekwo wa rọ ijọba apapọ lati pese aabo to yẹ fun awọn akọroyin ni ilana ti ofin gbe kalẹ.

Adajọ agba ni ile ẹjọ giga ti ijọba apapọ niluu Abuja, Inyang Ekwo ti pasẹ fun agbẹjọro agba lorilẹede Naijiria to tun jẹ minisita fun eto idajọ pe ki iwadii bẹrẹ pada lori iku gbajugbaja akọroyin, Dele Giwa.

Nigba to n gbe idajọ kalẹ, Adajọ Ekwo sọ pe wọn gbọdọ pese awọn to lọwọ ninu iku awọn akọroyin lorilẹede Naijiria.

Ọdun 1986 ni Dele Giwa jade laye lẹyin to tẹwọ gba ado oloro ti wọn fi sinu lẹta ni ọfisi rẹ nipinlẹ Eko.

Yatọ si igbẹjọ nipa Ọgbẹni Giwa, ile ẹjọ ọrọ naa kan gbogbo awọn to lọwọ ninu iku awọn akọroyin to n sisẹ wọn, ki wọn si fi iya jẹwọn ni ilana to ba ofin mu .

Adajọ Ekwo wa rọ ijọba apapọ lati pese aabo to yẹ fun awọn akọroyin ni ilana ti ofin gbe kalẹ.

Ojú rí kí n tó rí ètò tó mú èèyàn 51,000 wo sinimá tí mo fi gba àmì ẹ̀yẹ GWR ṣe – Omowunmi Dada

Aworan Omowunmi Dada pẹlu aworan idanimọ ajọ amiẹyẹ Guinness World Records lẹyin rẹ.

Ọmọwunmi Dada ni awọn fẹ fihan awọn eeyan pe kii ṣe ile iworan sinima nikan leyan le gbe sinima lọ fun wiwo.

Ọ̀rọ̀ láàárín Toyin Abraham àti Funke Akindele tún súyọ lórí ayélujára, ohun tí a mọ̀ rèé

Ninu fọnran naa, iroyin ni Bisgold n bu Funke Akindele, ti wọn si fẹsun kan pe niṣe ni Toyin Abraham n rẹrin-in labẹlẹ bi Bisgold ṣe n bu Funke Akindele.

Gomina naa lo sọ eyi nibi eto iburawọle fun saa keji iṣejọba rẹ, eyi to waye niluu Ado-Ekiti tii ṣe olu-ilu ipinlẹ Ekiti.

INEC Làá Hàn Mí: Èló ni àwọn olóṣèlú lè ná láti ṣe ìpolongo ìbò ní Naijiria? Ohun tí òfin sọ rèé

Ni bayii ti eto idibo gbogbogbo ọdun 2027 din diẹ ni oṣu mẹta pere ti ipolongon ibo si ti bẹrẹ, ajọ eleto dibo, INEC ti tan imọlẹ si iye ti ẹgbẹ oṣelu kọọkan le na lasiko yii.

Ibugbamu ipinle Edo ati Rivers mu ki ọpọ eeyan padanu okoowo wọn ti ọpọ si di alainile lori mọ.

Awọn ibugbamu yii mu ki ọpọ eeyan padanu okoowo wọn ti ọpọ si di alainile lori mọ.

"Èéfín ti gba gbogbo ara bàlúù náà lófurufú, tí kìí bá ṣe pé awakọ̀ bàlúù náà dùú dáadáa ni, aráàlú gan ìbá kú nínú ìjàmbá náà"

Ninu alaye ti wọn ṣe fun BBC, wọn ni awọn ṣakiyesi bi baluu naa ṣe n fi sihin sọhun bi ẹni pe awakọ rẹ n jijadu ko maa balẹ si ibi ti ko yẹ.

“Èéfín ti gba gbogbo ara bàlúù náà lófurufú, Tí kìí bá ṣe pé awakọ̀ bàlúù náà dùú dáadáa ni, aráàlú ga ìbá kú nínú ìjàmbá naáà”

Mi ò lè dìbò fún Peter Obi lọ́dún 2027, bẹ́ẹ̀ni kò sí aáwọ̀ láàrin wa - Gbadebo Rhodes-Vivour

Gbadebo Rhodes-Vivour wọ asọ toke tilẹ ati fila alawọ funfun, o ka ọwọ rẹ mejeeji mọ igba aya

Ṣé lóòótọ́ ni ẹbí Toluwanisings ń bẹ̀bẹ̀ ìrànwọ́ owó fún ìyàwó àtàwọn ọmọ rẹ̀ lẹ́yìn ikú olóògbé? Ohun tí a mọ̀ rèé

Iwe ilewọ kan to ti lu ori ayelujara pa bayii lo wa loju opo Instagram kan ti wọn n pe ni The Tolaoluwa Foundation eyi ti wọn fi n bẹbẹ iranwọ owo fun iyawo atawọn ọmọ oloogbe.

Kàyééfì: Nítorí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, àwọn jàǹdùkú ṣekú pa Bàbá, Ìyá àti ọmọ mẹ́rin n'Ibadan

Awọn afurasi mẹtẹẹta lo jokoo nilẹ yii, lasiko ti awọn ọlọpaa n fi oju wọn han fun awọn akọroyin

Ṣugbọn ni bayii, ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Oyo ti sọ pe ọwọ awọn ti tẹ afurasi mẹta to lọwọ ninu iku awọn idile naa, ati pe awọn ti bẹrẹ iwadii lori wọn.

Kò pẹ́ tí Toluwanisings kọrin tán níbi ìpàtẹ orin ẹ̀mí ló ṣubú lulẹ̀ – Amúgbálẹ̀gbẹ́

Toluwanisings ree nigba to wa laye, o de fila pẹlu aṣọ funfun to tun ni awọ olomi aro ninu, o lo aago sọwọ, bẹẹ lo n rẹrin musẹ

Ninu ifọrọwalẹwo kan to ṣe pẹlu gbajumọ oṣere, Biola Adebayo, Talk to B, sọ pe inu ẹsin Islam ni wọn bi oun si ati pe orin Fuji gan—an ni oun fi bẹrẹ.

Gomina Seyi Makinde la n fi ẹsun kan pe o da ibẹru oselu silẹ tori o ti pasẹ fawọn awakọ ero pe ki wọn maa lo ami idamọ ẹgbẹ oselu APM nikan soso lẹnu isẹ wọn - APC Oyo

Mọto ero kan wa nilẹ ti wọn kun ni awọ ọkọ ero nipinlẹ Oyo, wọn ti fọ gbogbo gilaasi rẹ, awọn ọmọ ẹgbẹ

Owurọ ọjọru ana ni isẹlẹ naa waye ni adugbo Molete nibi ti awọn ọmọ ẹgbẹ oselu Accord to lọwọọwọ si lati fi tijo tilu pade Oriyomi Hamzat to tilẹ UK de.

Awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ pannapanna ipinlẹ EKo ree lasiko ti wọn ṣẹṣẹ pa ina ọkọ agbepo to jona tan lori afara Otedola

Paul Mackenzie se akoso ile ijọsin rẹ fun ọdun mẹrindinlogun, ti ẹgbẹlẹgbẹ olujọsin si n tẹ le