Ìtumọ̀ 'Èmi Ló Kàn' rèé, ọmọ Naijiria ní láti já ìjọba àwarawa gbà padà lọ́dún 2027
Oríṣun àwòrán,Rauf Aregbesola/X
Published
wákàtí kan sẹ́yìn
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3
Minisita fun ọrọ abẹnu tẹlẹ ri, Ọgbẹni Rauf Aregbesola, ti ke pe awọn ọmọ Naijiria lati ja eto ijọba awarawa gba pada ninu eto idibo ọdun 2027 to n bọ.
Aregbesola to sọrọ ninu fidio kan eyi to wa loju opo X rẹ, ṣalaye ohun ti ''Emi Lo Kan'' ọrọ ti Aarẹ Bola Tinubu lo lasiko ipolongo ibo aarẹ ọdun 2023 tumọ si.
Niluu Abeokuta nipinlẹ Ogun ni Tinubu ti sọ pe ''Emi Lo Kan'' nigba to n ṣe ipolongo fun ibo aarẹ ọdun 2023.
Skip content and continue reading- "Èéfín ti gba gbogbo ara bàlúù náà lófurufú, tí kìí bá ṣe pé awakọ̀ bàlúù náà dùú dáadáa ni, aráàlú gan ìbá kú nínú ìjàmbá náà"wákàtí 4 sẹ́yìn
- Kí ló dé tó ṣe nira láti rí àjákù bàálù àti òkú àwọn ológun tó kú nínú bàálù tó já ní Igbokoda lẹ́yìn ọjọ́ méjì?wákàtí 3 sẹ́yìn
End of content
Amọ, Aregbesola ṣalaye pe Emi Lo kan tumọ si adari apaṣẹ wa a ti ẹnikẹni ko le yẹ lọwọ wo.
Aregbe ni ''awọn ọmọ Naijiria ni anfaani lati gba ijọba awarawa lọwọ awọn to ja a gba.
Ijọba apaṣẹ wa a ni Emi Lo Kan tumọ si lai deena pẹnu.
Emi Lo Kan jẹ eeyan to lagbara to le ṣe nnkan to ba wu u nigba kugba.
Emi Lo kan la n sọ yii, kii ṣe awa lo kan tabi ẹgbẹ wa lo kan.
Skip Èyítí A Ń Kà Jùlọ and continue readingÈyítí A Ń Kà Jùlọ- Kí ló dé tó ṣe nira láti rí àjákù bàálù àti òkú àwọn ológun tó kú nínú bàálù tó já ní Igbokoda lẹ́yìn ọjọ́ méjì?
- Wo orúkọ àwọn èèyàn tó pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ọkọ̀ òfurufú ọmogun Naijiria NAF 931 tó já ní Igbokoda l'Ondo
- Àlàyé lórí i bí ẹ̀ṣọ́ Amọtẹkun, àjọ DSS àti àpapọ̀ ọmọ ogun ṣe gbẹ̀mí adarí ISWAP nílùú Owo l'Ondo
- Seyi Makinde, Olubadan, sọ̀rọ̀ tuntun lórí àwọn àgùnbánirọ̀ Oyo tí wọ́n jí gbé ní Imo, àlàyé rèé
End of Èyítí A Ń Kà Jùlọ
''Emi'' jẹ ẹni to lagbara nla lati ṣe ijọba, mo fẹ kawọn ọmọ Naijiria mọ nnkan ti Emi Lo Kan tumọ si.
Kii ṣe nnkan ti a kan n fi eti wa gbọ lasan an mọ, nnkan to n ṣẹlẹ loju wa ni bayii.
Ṣugbọn awọn ọmọ Naijiria lanfaani lati dena ikọlu si ijọba awarawa.''
Skip X postAllow X content?This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Xcookie policyandprivacy policybefore accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.
End of X post