Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn,Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Published

31 Agẹmo 2025

Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí 5 sẹ́yìn

Lẹyin ọjọ meji ti baalu ọmogun Naijiria kan ti ja niluu Igbokoda nipinlẹ Ondo,

wọn ko tii ri oku awọn eeyan mẹẹdọgbọn ti wọn ba iṣẹlẹ ọhun lọ

O ma wa ga bayii o

BBC News Yoruba wa niluu Igbokoda lati maa mu akọtun iroyin wa fun yinlori bo ṣe n lọ

Pẹlu awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi to n wa oku awọn to wa ninu baluu naa

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Njẹ iwọ tiẹ mọ itumọ Emi Lo kan?

Bi ti bawo, ṣebi Aarẹ Bola Tinubu lo sọrọ naa lasiko ipolongo ibo aarẹ ọdun 2023

Bẹẹ ni, amọ, Gomina ipinlẹ Osun tẹlẹ, Ọgbẹni Rauf Aregbsola, ti sọtumọ Emi Lo Kan o?

Ki ni Arẹgbẹ sọ o?

Kan soju opo BBC News Yoruba ti o ba fẹ mọ

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ileeṣẹ ọkọ ofurufu Kenya Airways ti kede pe ọkunrin kan

To rinrin ajo lati ilu Nairobi si ilu Eko jade laye ki baluu to wọ to balẹ siluu Eko

Ileeṣẹ Kenya Airways ni o ku bi ogun iṣẹju ti baluu naa yoo ba siluu Eko ni ọkunrin yii ko le mi mọ

Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii…